Hymn E Wole Foba Ologo Julo
E wole foba ologo julo
e korin ipa ati ife re
alabo wa ni a teni igbani
on gbe nu ogo eleru niyin
E so tipare e so tore re
mole lasore gobi re orun
ara tin san ni keke binu re je
ipa ona re ni a kosile mo
Awa erupe alailera